Àwọn ẹ̀kà ẹ̀kọ́ èdè yorùbá

Ẹ̀kà 1: Ẹ̀kọ́ àwọn ẹ̀rọ kọ́ńpútà èdè :

  • Ẹ̀rọ̀ ìtẹ̀wé aláfọwọ́tẹ̀ èdè yorùbá

  • Ètò ẹ̀rọ ìtẹ̀wé aláfọwọ́tẹ̀

  • Fóònù ayára èdè yorùbá

  • Àwọn ètò kọ́ńpútà ti ìkọ́raẹnilẹ́kọ́ ẹ̀kọ́ èdè yorùbá

Ẹ̀kà 2 : Ẹ̀kọ́ ìbẹ̀rẹ̀ èdè yorùbá

  • Àṣà

  • Αlúfábẹ́ẹ̀tì

  • Ètò gbólóhùn ọ̀rọ̀ pẹ̀lú àwọn ẹ̀yà wọn

Ẹ̀kà 3 : Ẹ̀kọ́ àwọn ṣẹ̀ṣẹ̀bẹ̀rẹ̀

  • Ọ̀rọ̀ èdè ìpilẹ̀

  • Àwọn ohùn

  • Orúkọ

  • Ìṣẹ̀da ọ̀rọ̀

Ẹ̀kà 4 : Ẹ̀kọ́ ìjìnlẹ̀

  • Gírámà, ọ̀rọ̀-ìṣe, ọ̀rọ̀-Àpọ́nlé ,

  • Ìwádìí nínú àwọn ìwé àti àsọ-kíkọ́-di-kíkà

Ẹ̀kà 5 : Ẹ̀kọ́ ìjìnlẹ̀jìnlẹ̀

  • Ọ̀rọ̀-Αtọ́kùn àti Ọ̀rọ̀-Αsopọ̀

  • Àsìkò àti Ibá-ìṣẹ̀lẹ̀

  • Ìwádìí nínú àwọn ìwé àti àsọ-kíkọ́-di-kíkà

Ẹ̀kà 6 : Ẹ̀kọ́ ọ̀jọ̀gbọ́n èdè yorùbá

  • Àlàkalẹ̀ àti ìlànà ètò eré ìtàgé

  • Ìpàlọ́ọ́

  • Ìwé eré ìtàgé

Ẹ̀kà 7 : Ẹ̀kọ́ gíga yorùbá

  • Ìwádìí àwọn ìwé olùkọ̀wé èdè yorùbá

  • Àlàkalẹ̀ àti ìlànà

  • Òwe

Ẹ̀kà 8 : Ìlò ẹ̀kọ́ èdè yorùbá fún sáyẹ́nsì àwùjọ

  • Ẹ̀kọ́ àwọn ọ̀rọ̀ èdè ìpìlẹ̀ ti ìṣòwò, ìtàja,

    ìmọ̀ àwùjọ, ìbáaraẹnisọ̀rọ̀

Ẹ̀kà 9 : Ẹ̀kọ́ àwọn ọ̀rọ̀ èdè ìpìlẹ̀ ti ìmọ̀-ẹ̀rọ :

  • Ìmọ̀-ẹ̀rọ ìtanná, ìmọ̀-ẹ̀rọ iná mànàmáná,

    ìmọ̀-ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀, ẹ̀rọ ìṣiṣẹ́

Ẹ̀kà 10 : Ìṣe ṣiṣe

Ìdiyélé ìkẹ́kọ́ wa ni € 10 aago kan;

Àpàpọ̀ ohun èlò ìkẹ́kọ́ máa wà níka ọwọ́ yin ti ìdiyélé ẹ jẹ́ € 25, inú àpàpọ̀ yìí a máa ri : Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé èdè yorùbá, ètò ìtẹ̀wé fóònù ayára àti ètò ìkọ́raẹnilẹ́kọ́ èdè yorùbá.

 

  Ẹ ra ẹ̀rọ ìtẹ̀wé aláfọwọ́tẹ̀