Àwọn ẹ̀kọ́ wa nínú kọ́ńpútà ní àwọn ẹ̀kà mélòó kan.
Àwọn ara ẹ̀kọ́ wa :
-
Ìlànà àwọn ètò ìsọfúnni ( data ).
-
Àwòṣe àwọn ètò àti ìsọfúnni ( data ).
-
Ìdàgbàsókè àwọn ìsọfúnni ù data ).
-
Ètò kọ́ńpútà
-
Ìṣàkóso alásopọ̀ ( nẹ́tíwọkì )
-
Ìṣàkóso ilé-iṣẹ́
-
Ìtajà
-
Ìbánisọ̀rọ̀pọ̀
-
Èdè
-
Àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ