Sáyẹ́nsì ìṣàkóso àti ìṣòwò

Ìṣẹ́ ìṣàkóso, òwò àti ọrọ̀ ajé wà nínú àwọn ilé-iṣẹ́ gbogbo, tí a sì máa fún àwọn akẹ́kọ́ wa ní àǹfààní láti riṣẹ́ níbi gbogbo,  yálà nínú àwọn ilé-iṣẹ́ ìjọba tàbí ti àdání, àwọn iṣẹ́ wọ̀nyìí ni : ọgá ilé-iṣẹ́, olùṣírò owó, olùtajà,  àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

Àwọn iṣẹ́ wọ̀nyìí jẹ́ àwọn iṣẹ́ àwọn onímọ̀ọ́tótó, tí wọ́n sì ní ìmọ̀ ìbáraẹnisọ̀rọ̀ nínú ilé-iṣẹ́ tàbí pẹ̀lú àwọn oníbàárà. ìwé ẹ̀rí odún márùn ún ní yunifásítì ni a fi ṣé àwọn iṣẹ́ wọ̀nyìí.