I Àwọn ẹ̀kọ́ ìmọ̀-ẹ̀rọ-ìtanná ( ẹ̀lẹ́ktrónìkì )
Àwọn adàìtanná-níwọ̀nba ( Semikọ́ndọ́kítọ̀ )
Ẹ̀rọ ẹlẹ́nu méjì ( Díọ́dì )
Ẹ̀rọ ẹlẹ́nu mẹ́tà ( Tránsísítọ 1 )
Ìkọ́ṣẹ́ ìlò ẹ̀rọ ẹlẹ́nu mẹ́tà ( Tránsísítọ 2 )
Àtàkò ( Resistance )
Αlákòónú ( Kápásítọ̀ )
Àrunpọ̀ wáyà ( Self )
Àtàkò oní àdáyípadà ( Fríjísítánsì )
Àtàkò oní àdáyipadà ( Tẹrímísítánsì )
Àtàkò oní àdáyípadà ( Várísítánsì )
Ẹ̀rọ ẹlẹ́nu méjì Zener
Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́ alàìdúró
Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́ alálọ́bọ̀
Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́ ìgbíná
I I Ìmọ̀-ẹ̀rọ Àyára bíi àṣá ( Kọ́ńpútà )
1) Ẹ̀rọ Àyára bíi àṣá
Àwọn ẹ̀yà Àyára bíi àṣá ( Kọ́ńpútà )
2) Ẹ̀rọ ètò Àyára bíi àṣá
Αlúgórídímù ( Αlgorithm )
Αlákópọ̀ Java ( Java )
Αlákópọ̀ C++ ( C++ )