Technologie

Java Compilateur Orí 1

Java Akójọpọ̀                              Java Compiler                        Java Compilateur Orí 1 I Ìbẹ̀rẹ̀ Java jẹ́ ètòlẹ́sẹẹsẹ alákójọpọ̀ ti máa ń fún wa ni àǹfààní láti kọ ohun èlò ètò oríṣiríṣi, ó sì tún jẹ́ ètò alákójọpọ̀ tó tẹ̀ síwájú. Ọ̀nà méjì ni a ń fi kọ ohun èlò kọ́ńpútà  pẹ̀lú Java …

Java Compilateur Orí 1 Lire la suite »

Semikọ́ndọ́kítọ̀

Semikọ́ndọ́kítọ̀                              Semiconductor                        Semiconducteur Àwọn adàìtanná-níwọ̀nba  ( Semikọ́ndọ́kítọ̀ )   Ìbẹ̀rẹ̀ Inú ohun ìṣẹ̀da kan a lè rí bíi bílíọ́nù ọ̀nà bílíọ́nù atómù ( èròjà akéréjojú )  (ọta). Αtómù ní kúró ti àwọn ìtanná ( elekítírónì ) máa ń yí àyíká ẹ. Kúró yìí tún ní àwọn èròjà  » kékere méjì …

Semikọ́ndọ́kítọ̀ Lire la suite »

Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́ ìgbíná

Ẹ̀ńjìnì dísù                                   Diesel engine                                 moteur diesel Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́ oní ìgbóná abẹ́nu dísù Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́ oní ìgbóná abẹ́nu máa ń sọ agbára èròjà àpòpọ̀ àtẹ́gùn àti epo dísù di agbára ìṣiṣẹ́ tí a máa yìí àwọn nǹkan. Ẹ̀rọ yìí …

Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́ ìgbíná Lire la suite »

Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́ alálọ́bọ̀

Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́                                     ΑC engine                                 moteur CΑ   Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́ ( ẹ̀ńjìnì )  oní ìgbì iná alálọ́bọ̀ Àwọn ẹ̀rọ oní ìgbì iná mànàmáná jẹ́ àwọn ẹ̀rọ tó ṣe pàtàkì tí a ò tí gbé jáde rí, Àwọn ẹ̀ńjìnì wọ̀nyìí ni …

Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́ alálọ́bọ̀ Lire la suite »

Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́ alàìdúró

Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́                                           DC engine                                       moteur CC     Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́ ( ẹ̀ńjìnì )  oní ìgbì iná alàìdáwọ́dúró Tí a bá wò bí tí àwọn ọkọ̀ ojú irin oní iré gíga ṣe sáré gbà, tí iré …

Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́ alàìdúró Lire la suite »