Ìfẹ́nukò íntẹ́ẹ̀nẹ́tì ẹ̀kà 6 ( IPv6 )
Ìfẹ́nukò íntẹ́ẹ̀nẹ́tì ẹ̀kà 6 ( IPv6 )
Ìfẹ́nukò íntẹ́ẹ̀nẹ́tì ẹ̀kà 6 ( IPv6 )
Ìṣedọ́gba yíyàtọ̀ onígbọọrọ ìpele èkíní ( Differential equation ) Àlàyé ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ Àlàyé Ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ ni ìṣèdọ́gba ti ojútùú rẹ̀ jẹ́ isẹ́, tí àwọn àtúpalẹ̀ rẹ̀ sí wà nínú ìṣèdọ́gba náà. Àpẹẹrẹ Ìṣèdọ́gba f’(t)= 5 jẹ́ ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ ti f jẹ́ àìmọ̀, a tún lè kọ báyìí: y’=5 Ìṣèdọ́gba y’ = 2t2 – 3 tún …
Ìṣedọ́gba yíyàtọ̀ onígbọrọ ìpele èkèjì ( Differential equation ) 1 Àlàyá pẹ̀lú ìtúmọ̀ àwọn ọ̀rọ̀ Àwọn ìṣedọ́gba tí ìrísí wọn rí báyìí : (E) a(t)y”(t) + b(t)y’(t) + c(t)y(t) = f(t) Ni a ń pè ni ìṣedọ́gba yíyàtọ̀ onígbọọrọ yẹpẹrẹ y jẹ́ isẹ́ rere tí a ò mọ̀; a, b, c àti f jẹ́ àwọn …
1 Ọ̀rọ̀ ìṣáájú Ìpàrokò ni ohun èlò ti a máa sàbá lò fi dáàbòbò àwọn ìsọfúnni. Nígbà gbogbo Αlúgórídímù ìpàrokò ni a ń lò fi pàrokò àti ìṣàtúpalẹ̀ àrokò. Àwọn alúgórídímù wọ̀nyìí máa ń lo ìṣòro ìṣírò tó le láti rí abájáde rẹ̀, bìi ìsọdipúpọ̀ àwọn nọ́mbà àkọ́kọ́, àwọn alúgórídímù afọyè wò. Kọkọrọ ìpàrokò àti …
Àwọn onímúgbòòrò amóhun sisẹ́ wà lára àwọn èkà ẹ̀rọ ìtanná àgbáyé ti máa ń fún wa ni àǹfààní láti gbòòrò àwọn agbára ìṣiṣẹ́ àti agbára ìdènà iná mànàmáná. Α máa ṣàtúntò àwọn agbára wọ̀nyìí pẹ̀lú ìgbékiri iná mànàmáná ti a fi ṣàfikun ( àtàkò ìṣẹ̀lẹ̀, ìdènà amúnáwa ). Àwọn àfidámọ̀ onímúgbòòrò amóhun ṣisẹ́ máa jẹ́ …
Ọsílósíkọ́pù Ọsílọ́síkọ́pù jẹ́ ẹ̀rọ tí máa ń fún wa ni àǹfààní láti wọn àwọn ohun agbára, tí a á sì ṣàfihàn àwòrán àmì wọn lórí aṣàfihàn lọ́nà ìbàtan pẹ̀lú àsìkò, Α máa rí àmì yìí pẹ̀lú àwọn ìtọ́kasí t àti y lórí ọsílósíkọpù. Α máa ń rí àwọn ìlà tí ìrísí wọn jẹmọ́ ìṣe mathimátíkì …
Àwọn ọ̀wọ́ Àwọn ọ̀wọ́ ní àwọn àfidámọ̀ àti àwọn àlàkalẹ̀. Àwọn àfidámọ̀ jẹ́ àwọn oníyípadà àwọn ohun ọ̀wọ́ ( ìsọ̀wọ́ ), nínú ọ̀wọ́ a tún máa ri àwọn ètòlẹ́sẹẹsẹ tí wọn sì jẹ́ àwọn àlàkalẹ̀ ìṣe. Fún àwọn ohun ọ̀wọ́ kọ̀ọ̀kan àwọn àlàkalẹ̀ jẹ́ ọ̀kan náà, àmọ́ àwọn ìsọfúnni tó jẹ́ àwọn oníyípadà ló yàtọ̀. …
Ẹ̀kọ́ Αlúgórídímù Αlúgórídímù Nígbà tí a bá fẹ́ kọ alúgórídímù, ìgbésẹ̀ mẹ́ta ni a máa ń gbé. I Àwọn ìgbésẹ̀ mẹ́ta náà ni 1.1 ) Ìgbésẹ̀ kìíní Ìgbésẹ̀ àkọ́kọ́ ni kí a ṣàlàyé àwọn ohun ti a fẹ́ lò ( Àwọn oníyípadà, ìró , nọ́ḿbà..) 1.2 ) Ìgbésẹ̀ kejì A máa tú ìṣòro wa sí …
Ọkọ̀ òfurufú Plane Αvion Ìmọ̀ ọkọ̀ òfurufú Nígbà tí a bá máa lọ sí irin àjò tó jìnnà ọkọ̀ òfurufú ni a mán ń sàbá wọ̀, a ń …