Année : 2023
Ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ onígbọọrọ ìpele èkíní
Ìṣedọ́gba yíyàtọ̀ onígbọọrọ ìpele èkíní ( Differential equation ) Àlàyé ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ Àlàyé Ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ ni ìṣèdọ́gba ti ojútùú rẹ̀ jẹ́ isẹ́, tí àwọn àtúpalẹ̀ rẹ̀ sí wà nínú ìṣèdọ́gba náà. Àpẹẹrẹ Ìṣèdọ́gba f’(t)= 5 jẹ́ ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ ti f jẹ́ àìmọ̀, a tún lè kọ báyìí: y’=5 Ìṣèdọ́gba y’ = 2t2 – 3 tún …
Ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀
Ìṣedọ́gba yíyàtọ̀ onígbọrọ ìpele èkèjì ( Differential equation ) 1 Àlàyá pẹ̀lú ìtúmọ̀ àwọn ọ̀rọ̀ Àwọn ìṣedọ́gba tí ìrísí wọn rí báyìí : (E) a(t)y”(t) + b(t)y’(t) + c(t)y(t) = f(t) Ni a ń pè ni ìṣedọ́gba yíyàtọ̀ onígbọọrọ yẹpẹrẹ y jẹ́ isẹ́ rere tí a ò mọ̀; a, b, c àti f jẹ́ àwọn …
Ìpàrokò àti VPN
1 Ọ̀rọ̀ ìṣáájú Ìpàrokò ni ohun èlò ti a máa sàbá lò fi dáàbòbò àwọn ìsọfúnni. Nígbà gbogbo Αlúgórídímù ìpàrokò ni a ń lò fi pàrokò àti ìṣàtúpalẹ̀ àrokò. Àwọn alúgórídímù wọ̀nyìí máa ń lo ìṣòro ìṣírò tó le láti rí abájáde rẹ̀, bìi ìsọdipúpọ̀ àwọn nọ́mbà àkọ́kọ́, àwọn alúgórídímù afọyè wò. Kọkọrọ ìpàrokò àti …