Ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ onígbọọrọ ìpele èkíní

Ìṣedọ́gba yíyàtọ̀ onígbọọrọ ìpele èkíní ( Differential equation ) Àlàyé ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ Àlàyé Ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ ni ìṣèdọ́gba ti ojútùú rẹ̀ jẹ́ isẹ́,  tí àwọn àtúpalẹ̀ rẹ̀ sí wà nínú ìṣèdọ́gba náà. Àpẹẹrẹ Ìṣèdọ́gba f’(t)= 5 jẹ́ ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ ti f jẹ́ àìmọ̀, a tún lè kọ báyìí: y’=5 Ìṣèdọ́gba y’ = 2t2 – 3 tún …

Ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ onígbọọrọ ìpele èkíní Lire la suite »