Ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀
Ìṣedọ́gba yíyàtọ̀ onígbọrọ ìpele èkèjì ( Differential equation ) 1 Àlàyá pẹ̀lú ìtúmọ̀ àwọn ọ̀rọ̀ Àwọn ìṣedọ́gba tí ìrísí wọn rí báyìí : (E) a(t)y”(t) + b(t)y’(t) + c(t)y(t) = f(t) Ni a ń pè ni ìṣedọ́gba yíyàtọ̀ onígbọọrọ yẹpẹrẹ y jẹ́ isẹ́ rere tí a ò mọ̀; a, b, c àti f jẹ́ àwọn …