Mois : mai 2023

Ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ onígbọọrọ ìpele èkíní

Ìṣedọ́gba yíyàtọ̀ onígbọọrọ ìpele èkíní ( Differential equation ) Àlàyé ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ Àlàyé Ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ ni ìṣèdọ́gba ti ojútùú rẹ̀ jẹ́ isẹ́,  tí àwọn àtúpalẹ̀ rẹ̀ sí wà nínú ìṣèdọ́gba náà. Àpẹẹrẹ Ìṣèdọ́gba f’(t)= 5 jẹ́ ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ ti f jẹ́ àìmọ̀, a tún lè kọ báyìí: y’=5 Ìṣèdọ́gba y’ = 2t2 – 3 tún …

Ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ onígbọọrọ ìpele èkíní Lire la suite »

Ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀

Ìṣedọ́gba yíyàtọ̀ onígbọrọ ìpele èkèjì ( Differential equation ) 1 Àlàyá pẹ̀lú ìtúmọ̀ àwọn ọ̀rọ̀ Àwọn ìṣedọ́gba tí ìrísí wọn rí báyìí : (E)              a(t)y”(t) + b(t)y’(t) + c(t)y(t) = f(t) Ni a ń pè ni ìṣedọ́gba yíyàtọ̀ onígbọọrọ yẹpẹrẹ  y jẹ́ isẹ́ rere tí a ò mọ̀; a, b, c àti f jẹ́ àwọn …

Ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ Lire la suite »