Année : 2022

Àwọn onímúgbòòrò amóhun ṣiṣẹ́

Àwọn onímúgbòòrò amóhun sisẹ́ wà lára àwọn èkà ẹ̀rọ ìtanná àgbáyé ti máa ń fún wa ni àǹfààní láti gbòòrò àwọn agbára ìṣiṣẹ́ àti agbára ìdènà iná mànàmáná. Α máa ṣàtúntò àwọn agbára wọ̀nyìí pẹ̀lú ìgbékiri iná mànàmáná ti a fi ṣàfikun    ( àtàkò ìṣẹ̀lẹ̀, ìdènà amúnáwa ). Àwọn àfidámọ̀ onímúgbòòrò amóhun ṣisẹ́ máa jẹ́ …

Àwọn onímúgbòòrò amóhun ṣiṣẹ́ Lire la suite »

Ọsílósíkọ́pù

Ọsílósíkọ́pù Ọsílọ́síkọ́pù jẹ́ ẹ̀rọ tí máa ń fún wa ni àǹfààní láti wọn àwọn ohun agbára, tí a á sì ṣàfihàn àwòrán àmì wọn lórí aṣàfihàn lọ́nà ìbàtan pẹ̀lú àsìkò, Α máa rí àmì yìí pẹ̀lú àwọn  ìtọ́kasí t àti y lórí ọsílósíkọpù. Α máa ń rí àwọn ìlà tí ìrísí wọn jẹmọ́ ìṣe mathimátíkì …

Ọsílósíkọ́pù Lire la suite »

Java Compilateur Orí 2

Àwọn ọ̀wọ́ Àwọn ọ̀wọ́ ní àwọn àfidámọ̀ àti àwọn àlàkalẹ̀. Àwọn àfidámọ̀ jẹ́ àwọn oníyípadà àwọn ohun ọ̀wọ́ ( ìsọ̀wọ́ ), nínú ọ̀wọ́ a tún máa ri àwọn ètòlẹ́sẹẹsẹ tí wọn sì jẹ́ àwọn àlàkalẹ̀ ìṣe. Fún àwọn ohun ọ̀wọ́ kọ̀ọ̀kan àwọn àlàkalẹ̀ jẹ́ ọ̀kan náà, àmọ́ àwọn ìsọfúnni tó jẹ́ àwọn oníyípadà ló yàtọ̀. …

Java Compilateur Orí 2 Lire la suite »

Αlúgórídímù

Ẹ̀kọ́ Αlúgórídímù Αlúgórídímù Nígbà tí a bá fẹ́ kọ alúgórídímù, ìgbésẹ̀ mẹ́ta ni a máa ń gbé. I Àwọn ìgbésẹ̀ mẹ́ta náà ni 1.1 )   Ìgbésẹ̀ kìíní Ìgbésẹ̀ àkọ́kọ́ ni  kí a ṣàlàyé àwọn ohun  ti a fẹ́ lò (  Àwọn oníyípadà,  ìró , nọ́ḿbà..) 1.2 )  Ìgbésẹ̀ kejì A máa tú  ìṣòro wa sí …

Αlúgórídímù Lire la suite »

Java Compilateur Orí 1

Java Akójọpọ̀                              Java Compiler                        Java Compilateur Orí 1 I Ìbẹ̀rẹ̀ Java jẹ́ ètòlẹ́sẹẹsẹ alákójọpọ̀ ti máa ń fún wa ni àǹfààní láti kọ ohun èlò ètò oríṣiríṣi, ó sì tún jẹ́ ètò alákójọpọ̀ tó tẹ̀ síwájú. Ọ̀nà méjì ni a ń fi kọ ohun èlò kọ́ńpútà  pẹ̀lú Java …

Java Compilateur Orí 1 Lire la suite »

Ọkọ̀ òfurufú

Ọkọ̀ òfurufú                                         Plane                                                      Αvion Ìmọ̀ ọkọ̀ òfurufú Nígbà tí a bá máa lọ sí irin àjò tó jìnnà ọkọ̀ òfurufú ni a mán ń sàbá wọ̀, a ń …

Ọkọ̀ òfurufú Lire la suite »