Mois : novembre 2021

Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́ ìgbíná

Ẹ̀ńjìnì dísù                                   Diesel engine                                 moteur diesel Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́ oní ìgbóná abẹ́nu dísù Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́ oní ìgbóná abẹ́nu máa ń sọ agbára èròjà àpòpọ̀ àtẹ́gùn àti epo dísù di agbára ìṣiṣẹ́ tí a máa yìí àwọn nǹkan. Ẹ̀rọ yìí …

Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́ ìgbíná Lire la suite »

Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́ alálọ́bọ̀

Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́                                     ΑC engine                                 moteur CΑ   Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́ ( ẹ̀ńjìnì )  oní ìgbì iná alálọ́bọ̀ Àwọn ẹ̀rọ oní ìgbì iná mànàmáná jẹ́ àwọn ẹ̀rọ tó ṣe pàtàkì tí a ò tí gbé jáde rí, Àwọn ẹ̀ńjìnì wọ̀nyìí ni …

Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́ alálọ́bọ̀ Lire la suite »