Non classé

Semikọ́ndọ́kítọ̀ ( Semiconductor )

Semikọ́ndọ́kítọ̀                              Semiconductor                        Semiconducteur Àwọn adàìtanná-níwọ̀nba  ( Semikọ́ndọ́kítọ̀ )   Ìbẹ̀rẹ̀ Inú ohun ìṣẹ̀da kan a lè rí bíi bílíọ́nù ọ̀nà bílíọ́nù atómù ( èròjà akéréjojú )  (ọta). Αtómù ní kúró ti àwọn ìtanná ( elekítírónì ) máa ń yí àyíká ẹ. Kúró yìí tún ní àwọn èròjà ” kékere méjì …

Semikọ́ndọ́kítọ̀ ( Semiconductor ) Read More »

Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́ alàìdúró

Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́                                           DC engine                                       moteur CC     Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́ ( ẹ̀ńjìnì )  oní ìgbì iná alàìdáwọ́dúró Tí a bá wò bí tí àwọn ọkọ̀ ojú irin oní iré gíga ṣe sáré gbà, tí iré …

Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́ alàìdúró Read More »

Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́ alálọ́bọ̀

Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́                                     ΑC engine                                 moteur CΑ   Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́ ( ẹ̀ńjìnì )  oní ìgbì iná alálọ́bọ̀ Àwọn ẹ̀rọ oní ìgbì iná mànàmáná jẹ́ àwọn ẹ̀rọ tó ṣe pàtàkì tí a ò tí gbé jáde rí, Àwọn ẹ̀ńjìnì wọ̀nyìí ni …

Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́ alálọ́bọ̀ Read More »

Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́ ìgbíná

Ẹ̀ńjìnì dísù                                   Diesel engine                                 moteur diesel Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́ oní ìgbóná abẹ́nu dísù Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́ oní ìgbóná abẹ́nu má   a ń sọ agbára èròjà àpòpọ̀ àtẹ́gùn àti epo dísù di agbára ìṣiṣẹ́ tí a máa yìí àwọn nǹkan. Ẹ̀rọ …

Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́ ìgbíná Read More »