Semikọ́ndọ́kítọ̀ ( Semiconductor )
Semikọ́ndọ́kítọ̀ Semiconductor Semiconducteur Àwọn adàìtanná-níwọ̀nba ( Semikọ́ndọ́kítọ̀ ) Ìbẹ̀rẹ̀ Inú ohun ìṣẹ̀da kan a lè rí bíi bílíọ́nù ọ̀nà bílíọ́nù atómù ( èròjà akéréjojú ) (ọta). Αtómù ní kúró ti àwọn ìtanná ( elekítírónì ) máa ń yí àyíká ẹ. Kúró yìí tún ní àwọn èròjà ” kékere méjì …