Àwọn ìwé ẹ̀kọ́ ìmọ̀-ẹ̀rọ-ìtanná ( Electronic technology )

1) Àwọn adàìtanná-níwọ̀nba  ( Semikọ́ndọ́kítọ̀ )
Semiconductor
Semiconducteur

 

2) Ẹ̀rọ ẹlẹ́nu méjì ( Díọ́dì )
Diode
Diode

 

3) Ẹ̀rọ ẹlẹ́nu mẹ́tà ( Transitọ 1 )
Transistor
Transistor

 

4) Ìkọ́ṣẹ́ ìlò ẹ̀rọ ẹlẹ́nu mẹ́tà ( Tránsísítọ 2  )
Transistor Exploitation
Exploitation des transistors

 

5) Díọ́dì Zener ( Diode )
Zener Diode
Diode Zener

 

6)  Ìmọ̀ ojú àmì ìṣiṣẹ́ Ìṣípòtakò
Operating point of a transistor
Point de fonctionnement d’un transistor

 

7) Àrunpọ̀ wáyà ( Sẹ́lífì )

Self
Bobine

 

8)  Àwọn àyíká iná mànàmáná
Electrical circuits
Les circuits électriques

 

9) Ẹ̀rọ onímúgbòòrò

Operationel Amplifier
Amplificateur opérationnel

 

10) Arduino
Microcontroller
Microcontroleur