Àwọn ẹ̀kọ́ ìmọ̀-ẹ̀rọ-iná mànàmáná ( Electric technology )

Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́ ìgbíná
Diesel engine
Moteur diesel

 

Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́ alálọ́bọ̀
ΑC Engine    ( Αlternating courant )
Moteur CΑ    ( Courant alternatif )

 

Ẹ̀rọ àmóhun ṣiṣẹ́ alàìdúró
DC Engine
Moteur CC

 

Àtàkò oní àdáyípadà ( Várísítánsì ) ( ẹ ṣi níbi )
Varistors
Varistances

 

Àrunpọ̀ wáyà ( Sẹ́lífì )
Self
Bonbine

 

Àtàkò oní àdáyipadà ( Tẹrímísítánsì )

Thermistor
Thermistance

 

Àtàkò oní àdáyípadà ( Fríjísítánsì)
Frigistance
Frigistances

 

Αlákòónú ( Kápásítọ̀ )
Capacitor
Condensateur

 

Àtàkò
Resistance
Résistances