Àjọṣepọ̀

OMOLUWABI jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ gíga ìwàdìí ìmọ̀-ẹ̀rọ .
Ìmọ̀ran wa ni ìtànkálẹ̀ ìmọ̀-ẹ̀rọ nínú èdè yorùbá tàbí èdè Áfíríká mìn-ín. Èyí ni  á fún wa ni àǹfààní láti fún àwọn ọmọ wa ni iṣẹ́. Ilé-ẹ̀kọ́ OMOLUWΑBI ti ṣètò ìbáṣepò pẹ́lù àwọn YUNIFÁSÍTÌ ìlú FΑRΑNSÉ, KÁNÁDÀ, àti ÁMẸ́RÍKÁ àti àwọn ilé-isẹ́ ìjọba àti ti adání. Gbogbo àwọn akẹ́kọ́ ti máa ń ṣe ìwàdi ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga OMOLUWΑBI lè ní àǹfààní láti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn YUNIFÁSÍTÌ abáyé fún páṣípàrọ̀ ìmọ̀-ẹ̀rọ.