Ìṣedọ́gba yíyàtọ̀ onígbọọrọ ìpele èkíní
( Differential equation )
-
Àlàyé ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀
Àlàyé
Ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ ni ìṣèdọ́gba ti ojútùú rẹ̀ jẹ́ isẹ́, tí àwọn àtúpalẹ̀ rẹ̀ sí wà nínú ìṣèdọ́gba náà.
Àpẹẹrẹ
-
Ìṣèdọ́gba f’(t)= 5 jẹ́ ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ ti f jẹ́ àìmọ̀, a tún lè kọ báyìí: y’=5
-
Ìṣèdọ́gba y’ = 2t2 – 3 tún jẹ́ ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ abájáde jẹ́ iṣẹ́ y tí àtúpalẹ̀ rẹ̀ 2t2 + 3
-
Ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ irú y’ = f
Àlàyé : Nígbà tí a bá ròronuwòye iṣẹ́ f tí a ṣàlàyé nínú ìkókó I, iṣẹ́ g jẹ́ ojútùú ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ y’ = f nígbà tí g’(t) = f(t) nìkan.
Àbùdá :
Nígbà tí a bá sọ pé F jẹ́ orísun f, èyí túmọ̀ sí pé F jẹ́ ojútùú ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ y’ = f
-
Ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ irú y’= ay
Àbùdá :
Àwọn ojútùú ìṣèdọ́gba y’ = ay a ∈ R ni àwọn isẹ́ tí ìrísí wọn jẹ́
t à Ceat tí C jẹ́ aláìṣeyípadà èyíkeyí
Àbùdá :
Àwọn ojútùú ìṣèdọ́gba y’ = ay a ∈ R ni àwọn isẹ́ tí ìrísí wọn jẹ́
t à Ceat tí C jẹ́ aláìṣeyípadà èyíkeyí
Déìṣàfíhàn :
-
Nígbà tí a bá ròronuwòye iṣẹ́ f tí a ṣàlàyé sórí R pẹ̀lú f(t) = Ceat
f’(t) = Caeat = af(t)f’(t) = af(t)
f jẹ́ ojútùú ìṣèdọ́gbà y’= ay
-
Jíjùmọ̀:
Nígbà tí f jẹ́ ojútùú ìṣèdọ́gbà y’ = ay, tí iṣẹ́ g jẹ́ iṣẹ́ tí a ṣàlàyé sórí R pẹ̀lú
g(t) = Ce-at * f(t)
Nígbà tí iṣẹ́ jẹ́ ojútùú ìṣèdọ́gba y’ = ay
f’(t) = af(t)
Nígbà yẹn
g’(t) = -ae-at *f(t) + e-at *f’(t)
= – e-at *af(t) + e-at*f’(t)
= – e-at *f’(t) + e-at*f’(t)
= 0
Èyí tó túmọ̀ sí g jẹ́ iṣẹ́ aláìṣeyípadà
Nígbà tí e-at*f(t) = C èyí tó túmọ̀ sì
f(t) = C x 1/ e-at = Ceat
Àlàkalẹ̀ : Ìyànju ìṣedọ́gba yíyàtọ̀ irú y’ = ay
Nígbà tí ẹ bá ròronúwòye ìṣèdọ́gba yìyàtọ̀ 3y’ + 5y = 0
a) Ẹ ṣàwárí àwọn irúfẹ́ ìrísí àwọn ojútùú ìṣèdọ́gba
-
Ẹ ṣàwárí àwọn ìlà mélòó kan tó jẹ́ ojútùú iṣẹ́ pẹ̀lú ẹ̀rọ ìṣirò tàbí ètòlẹ́sẹesẹ̀
-
Ẹ ṣàwárí ojútùú ẹyọ kan tí f(1) = 2
Ojútùú : ?
Àbùdá :
Nígbà tí f àti g bá jẹ́ ojútùú ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ y’=ay, èyí túmọ̀ sí pé àwọn f + g àti kf kЄ R jẹ́ ojútùú ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀.
Déìṣàfíhàn:
(𝑓 + 𝑔) » = 𝑓 » + 𝑔 » = 𝑎𝑓 + 𝑎𝑔 = 𝑎(𝑓 + 𝑔)
– (𝑘𝑓) » = 𝑘𝑓 » = 𝑘 × 𝑎𝑓 = 𝑎(𝑘𝑓
Àbùdá :
Iṣẹ́ tà -b/a jẹ́ ojútùú ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ y’ = ay + b ( a≠ 0 ) ojútùú yìí ni ojútùú àkànṣe aláìṣeyípadà.
-
Ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ irúfẹ́ y’ = ay + b
Àbùdá :
Iṣẹ́ tà -b/a jẹ́ ojútùú ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ y’ = ay + b ( a≠ 0 ) ojútùú yìí ni ojútùú àkànṣe aláìṣeyípadà.
Àbùdá :
Iṣẹ́ tà -b/a jẹ́ ojútùú ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ y’ = ay + b ( a≠ 0 ) ojútùú yìí ni ojútùú àkànṣe
aláìṣeyípadà.
Déìṣàfihàn :
Àgbékalẹ̀ g(t) = -b/a, ìyẹn g’(t) = 0 àmọ́ ag(t) +b = ax(-b/a) + b = b-b =0=ǵ(t)
Nítorí náà g’(t) = ag(t) + b
Déìṣàfihàn :
Àgbékalẹ̀ g(t) = -b/a, ìyẹn g’(t) = 0 àmọ́ ag(t) +b = ax(-b/a) + b = b-b =0=ǵ(t)
Nítorí náà g’(t) = ag(t) + b
Déìṣàfihàn :
Àgbékalẹ̀ g(t) = -b/a, ìyẹn g’(t) = 0 àmọ́ ag(t) +b = ax(-b/a) + b = b-b =0=ǵ(t)
Nítorí náà g’(t) = ag(t) + b
Déìṣàfihàn :
Àgbékalẹ̀ g(t) = -b/a, ìyẹn g’(t) = 0 àmọ́ ag(t) +b = ax(-b/a) + b = b-b =0=ǵ(t)
Nítorí náà g’(t) = ag(t) + b
Déìṣàfihàn :
Àgbékalẹ̀ g(t) = -b/a, ìyẹn g’(t) = 0 àmọ́ ag(t) +b = ax(-b/a) + b = b-b =0=ǵ(t)
Nítorí náà g’(t) = ag(t) + b
Àbùdá : Àwọn ojútùú ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ 𝑦’ = 𝑎𝑦 + 𝑏 (𝑎 ≠ 0) ni àwọn isẹ́ tí wọ́n
ní ìrísí t ⟼ 𝐶𝑒at− b/a
Iṣẹ́ àdáṣe
Àlàkalẹ̀ : Ìyànju ìṣedọ́gba yíyàtọ̀ irú y’ = ay + b
Nígbà tí ẹ bá ròronuwòye ìṣèdọ́gba yìyàtọ̀ ( E ) 2y’ – y = 3
a) Ẹ ṣàwárí ojútùú àkànse ti ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ ( E )
-
Ẹ ṣàwárí ìrísí àwọn gbogbo ojútùú ti ìṣèdọ́gba yíyàtọ́ y’ = 1/2y
-
Ẹ ṣàfihàn ìrísí àwọn ojútùú ìsèdọ́gba ( E )
-
Ẹ ṣàwárí ojútùú ẹyọ kan iṣẹ́ f nígbà tí f(0) = -1