Ìfẹ́nukò íntẹ́ẹ̀nẹ́tì ẹ̀kà 6 ( IPv6 )
IPv6 jẹ́ ẹ̀yà tuntun ìfẹnukò íntẹ́nẹ́ẹ̀tì tó tẹ̀lé IPv4 tí á gbà ààyè rẹ lọ́jọ́ wájú. 3°) Àwọn ìyàtọ láàrin IPv4 àti IPv6 ni wọ̀nyìí : Αgbára àdírẹ́ẹ̀sì lọ sókè, gígùn àdírẹ́ẹ̀sì kúrò ni bíìtì 32 dé bíìtì 128. Àfikún àwọn èbúté ìtọ́ka sí pẹ̀lú àdáse ìgbékalẹ̀ àwọn àdírẹ́ẹ̀sì. Ìdàgbàsókè ìfisọ́nà ìtànkalẹ̀ pẹ̀lú àfikún …