Ìmọ̀ ojú àmì ìṣiṣẹ́ Ìṣípòtakò

Ìmọ̀  ojú àmì ìṣiṣẹ́ transitọ ( Ìṣípòtakò ) 1  Ìmúlò àwọn ìlà àfidámọ̀ Ìṣípòtakò ( Transitọ ) 1.1 Àwárí ojú àmì ìṣiṣẹ́ ìṣipòpadà ( transitọ )   A máa ń lò àwọn àfidámọ̀ àwọn trànsitọ fi mọ̀ ojú àmì ìsiṣẹ́ wọn. Èyí máa jẹ́ ká mọ̀ àwọn agbára iná mànàmáná tí a ń lò. Àwọn àfidámọ̀ …

Ìmọ̀ ojú àmì ìṣiṣẹ́ Ìṣípòtakò Read More »