Αljẹ́brà bóòlù pẹ̀lú àwọn iṣẹ́ tó jẹ mọ́
1 Àfidámọ̀ Α ṣàlàyé aljẹ́brà bóòlù sórí àkójọ E2 tí àwọn ìdá-ìpìlẹ̀ jẹ́ { 0, 1 }. Ìtò tó wà láàrin àwọn òùnkà ni 0 < 1 àti àwọn ìṣìrò ìpìlẹ̀ mẹ́ta. Ìyòdì tí a ṣàlàyé sórí àtẹ 1 jẹ́ iṣẹ́ E2 —> E2. Àwọn iṣẹ́ àpapọ̀ tí a ń pè ni TÀBÍ, tó sì …