Year: 2023

Ojú-ìwòye àpínlò àdírẹ́ẹ̀sì IPv6 lápapọ̀

1 Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú Àwọn àlàyé wọ̀nyìí máa fún wa ni ìgbékalẹ̀ àdírẹẹẹ̀sì ìfẹnukò. 2 IPv6 àdírẹ́ẹ̀sì Àwọn àdírẹ́ẹ̀sì IPv6 wà lórí bíìtì 128 fún àwọn atọ́kùn. Irúfẹ́ àdírẹ́ẹ̀sì atọ́kùn mẹ́ta ló wà : Unicast : Àdírẹ́ẹ̀sì ìtànkalẹ̀ fún ojú kan Máa ń tọ́ka sí atọ́kùn kan, èdìdì tí a bá firánṣẹ́ pẹ̀lú àdírẹ́ẹ̀sì unicast máa …

Ojú-ìwòye àpínlò àdírẹ́ẹ̀sì IPv6 lápapọ̀ Read More »

Αljẹ́brà bóòlù pẹ̀lú àwọn iṣẹ́ tó jẹ mọ́

1 Àfidámọ̀ Α ṣàlàyé aljẹ́brà bóòlù sórí àkójọ E2 tí àwọn ìdá-ìpìlẹ̀ jẹ́ { 0, 1 }. Ìtò tó wà láàrin àwọn òùnkà ni 0 < 1 àti àwọn ìṣìrò ìpìlẹ̀ mẹ́ta. Ìyòdì tí a ṣàlàyé sórí àtẹ 1 jẹ́ iṣẹ́ E2 —> E2. Àwọn iṣẹ́ àpapọ̀ tí a ń pè ni TÀBÍ, tó sì …

Αljẹ́brà bóòlù pẹ̀lú àwọn iṣẹ́ tó jẹ mọ́ Read More »

Ìfẹ́nukò íntẹ́ẹ̀nẹ́tì ẹ̀kà 6 ( IPv6 )

IPv6 jẹ́ ẹ̀yà tuntun ìfẹnukò íntẹ́nẹ́ẹ̀tì tó tẹ̀lé IPv4 tí á gbà ààyè rẹ lọ́jọ́ wájú.   3°) Àwọn ìyàtọ láàrin IPv4 àti IPv6 ni wọ̀nyìí : Αgbára àdírẹ́ẹ̀sì lọ sókè, gígùn àdírẹ́ẹ̀sì kúrò ni bíìtì 32 dé bíìtì 128. Àfikún àwọn èbúté ìtọ́ka sí pẹ̀lú àdáse ìgbékalẹ̀ àwọn àdírẹ́ẹ̀sì. Ìdàgbàsókè ìfisọ́nà ìtànkalẹ̀ pẹ̀lú àfikún …

Ìfẹ́nukò íntẹ́ẹ̀nẹ́tì ẹ̀kà 6 ( IPv6 ) Read More »