Java àkójọpọ̀ Orí 2
Àwọn ọ̀wọ́ Àwọn ọ̀wọ́ ní àwọn àfidámọ̀ àti àwọn àlàkalẹ̀. Àwọn àfidámọ̀ jẹ́ àwọn oníyípadà àwọn ohun ọ̀wọ́ ( ìsọ̀wọ́ ), nínú ọ̀wọ́ a tún máa ri àwọn ètòlẹ́sẹẹsẹ tí wọn sì jẹ́ àwọn àlàkalẹ̀ ìṣe. Fún àwọn ohun ọ̀wọ́ kọ̀ọ̀kan àwọn àlàkalẹ̀ jẹ́ ọ̀kan náà, àmọ́ àwọn ìsọfúnni tó jẹ́ àwọn oníyípadà ló yàtọ̀. …