Month: April 2022

Java àkójọpọ̀ Orí 2

Àwọn ọ̀wọ́ Àwọn ọ̀wọ́ ní àwọn àfidámọ̀ àti àwọn àlàkalẹ̀. Àwọn àfidámọ̀ jẹ́ àwọn oníyípadà àwọn ohun ọ̀wọ́ ( ìsọ̀wọ́ ), nínú ọ̀wọ́ a tún máa ri àwọn ètòlẹ́sẹẹsẹ tí wọn sì jẹ́ àwọn àlàkalẹ̀ ìṣe. Fún àwọn ohun ọ̀wọ́ kọ̀ọ̀kan àwọn àlàkalẹ̀ jẹ́ ọ̀kan náà, àmọ́ àwọn ìsọfúnni tó jẹ́ àwọn oníyípadà ló yàtọ̀. …

Java àkójọpọ̀ Orí 2 Read More »

Αlúgórídímù

Ẹ̀kọ́ Αlúgórídímù Αlúgórídímù Nígbà tí a bá fẹ́ kọ alúgórídímù, ìgbésẹ̀ mẹ́ta ni a máa ń gbé. I Àwọn ìgbésẹ̀ mẹ́ta náà ni 1.1 )   Ìgbésẹ̀ kìíní Ìgbésẹ̀ àkọ́kọ́ ni  kí a ṣàlàyé àwọn ohun  ti a fẹ́ lò (  Àwọn oníyípadà,  ìró , nọ́ḿbà..) 1.2 )  Ìgbésẹ̀ kejì A máa tú  ìṣòro wa sí …

Αlúgórídímù Read More »