Year: 2022

Java àkójọpọ̀ Orí 2

Àwọn ọ̀wọ́ Àwọn ọ̀wọ́ ní àwọn àfidámọ̀ àti àwọn àlàkalẹ̀. Àwọn àfidámọ̀ jẹ́ àwọn oníyípadà àwọn ohun ọ̀wọ́ ( ìsọ̀wọ́ ), nínú ọ̀wọ́ a tún máa ri àwọn ètòlẹ́sẹẹsẹ tí wọn sì jẹ́ àwọn àlàkalẹ̀ ìṣe. Fún àwọn ohun ọ̀wọ́ kọ̀ọ̀kan àwọn àlàkalẹ̀ jẹ́ ọ̀kan náà, àmọ́ àwọn ìsọfúnni tó jẹ́ àwọn oníyípadà ló yàtọ̀. …

Java àkójọpọ̀ Orí 2 Read More »

Αlúgórídímù

Ẹ̀kọ́ Αlúgórídímù Αlúgórídímù Nígbà tí a bá fẹ́ kọ alúgórídímù, ìgbésẹ̀ mẹ́ta ni a máa ń gbé. I Àwọn ìgbésẹ̀ mẹ́ta náà ni 1.1 )   Ìgbésẹ̀ kìíní Ìgbésẹ̀ àkọ́kọ́ ni  kí a ṣàlàyé àwọn ohun  ti a fẹ́ lò (  Àwọn oníyípadà,  ìró , nọ́ḿbà..) 1.2 )  Ìgbésẹ̀ kejì A máa tú  ìṣòro wa sí …

Αlúgórídímù Read More »

Alákójọpọ̀ Java 

Java Akójọpọ̀                              Java Compiler                        Java Compilateur Orí 1 I Ìbẹ̀rẹ̀ Java jẹ́ ètòlẹ́sẹẹsẹ alákójọpọ̀ ti máa ń fún wa ni àǹfààní láti kọ ohun èlò ètò oríṣiríṣi, ó sì tún jẹ́ ètò alákójọpọ̀ tó tẹ̀ síwájú. Ọ̀nà méjì ni a ń fi kọ ohun èlò kọ́ńpútà  pẹ̀lú Java …

Alákójọpọ̀ Java  Read More »

Semikọ́ndọ́kítọ̀

Semikọ́ndọ́kítọ̀                              Semiconductor                        Semiconducteur Àwọn adàìtanná-níwọ̀nba  ( Semikọ́ndọ́kítọ̀ )   Ìbẹ̀rẹ̀ Inú ohun ìṣẹ̀da kan a lè rí bíi bílíọ́nù ọ̀nà bílíọ́nù atómù ( èròjà akéréjojú )  (ọta). Αtómù ní kúró ti àwọn ìtanná ( elekítírónì ) máa ń yí àyíká ẹ. Kúró yìí tún ní àwọn èròjà ” kékere méjì …

Semikọ́ndọ́kítọ̀ Read More »

Ọkọ̀ Òfurufú

Ọkọ̀ òfurufú                                         Plane                                                      Αvion   Ìmọ̀ ọkọ̀ òfurufú   Tí a bá máa lọ sí irin àjò tó jìnnà ọkọ̀ òfurufú ni a mán ń sàbá wọ̀, a …

Ọkọ̀ Òfurufú Read More »