Ẹ̀rọ ẹlẹ́nu méjì Zener
Díọ́dì Zener ( Diode )
Díọ́dì Zener ( Diode )
Àtàkò oní àdáyípadà ( Thermistance ) ( ẹ ṣi níbi )
Àtàkò oní àdáyípadà ( Várísítánsì ) ( ẹ ṣi níbi )
Àtàkò oní àdáypadà ( ẹ ṣi í níbi )
Àwọn àrunpọ̀ wáyà / Sẹ́lífì (ìṣẹ̀dá òòfà ) Àrunpọ̀ wáyà ti a lọ mọ́ rìbìtì ni a ń pè ni sẹ́lífì ( oní ṣẹ̀da agbára òòfà ). Nínú àwọn àyíka ìgbì iná oníyípadà, sẹ́lífì wà bíi àtàkò ; ti a bá lò ó pẹ̀lú alákòónú nínú àyíka àti àwọn ẹ̀rọ mì ín tó ń ṣiṣẹ́, …
Ìkọ́ṣẹ́ ìlò ẹ̀rọ ẹlẹ́nu mẹ́tàs ( Ẹ ṣí í níbi )