Àwọn akẹ́kọ́ wa lè rí ìrànlọ́wọ́ láti ọdọ wa fún àwọn owó ẹ̀kọ́ wọn.
Àwọn ọ̀nà àti rí owó iléwé ni wọ̀nyìí :
- Àpò owó ẹ̀kọ́
- Owó yíya fi kàwé
Àwọn akẹ́kọ́ tó bá pínnu láti béèrè ìrànlọ́wọ́, wọ́n máa béèrè àpilẹ̀kọ wọn ní offíìsì wa tó wà ni 23/25 rue Jean-Jacques Rousseau – 75001 PARIS