Ẹ̀kà 1: Ẹ̀kọ́ àwọn ẹ̀rọ kọ́ńpútà èdè :
-
Ẹ̀rọ̀ ìtẹ̀wé aláfọwọ́tẹ̀ èdè yorùbá
-
Ètò ẹ̀rọ ìtẹ̀wé aláfọwọ́tẹ̀
-
Fóònù ayára èdè yorùbá
-
Àwọn ètò kọ́ńpútà ti ìkọ́raẹnilẹ́kọ́ ẹ̀kọ́ èdè yorùbá
Ẹ̀kà 2 : Ẹ̀kọ́ ìbẹ̀rẹ̀ èdè yorùbá
-
Àṣà
-
Αlúfábẹ́ẹ̀tì
-
Ètò gbólóhùn ọ̀rọ̀ pẹ̀lú àwọn ẹ̀yà wọn
Ẹ̀kà 3 : Ẹ̀kọ́ àwọn ṣẹ̀ṣẹ̀bẹ̀rẹ̀
-
Ọ̀rọ̀ èdè ìpilẹ̀
-
Àwọn ohùn
-
Orúkọ
-
Ìṣẹ̀da ọ̀rọ̀
Ẹ̀kà 4 : Ẹ̀kọ́ ìjìnlẹ̀
-
Gírámà, ọ̀rọ̀-ìṣe, ọ̀rọ̀-Àpọ́nlé ,
-
Ìwádìí nínú àwọn ìwé àti àsọ-kíkọ́-di-kíkà
Ẹ̀kà 5 : Ẹ̀kọ́ ìjìnlẹ̀jìnlẹ̀
-
Ọ̀rọ̀-Αtọ́kùn àti Ọ̀rọ̀-Αsopọ̀
-
Àsìkò àti Ibá-ìṣẹ̀lẹ̀
-
Ìwádìí nínú àwọn ìwé àti àsọ-kíkọ́-di-kíkà
Ẹ̀kà 6 : Ẹ̀kọ́ ọ̀jọ̀gbọ́n èdè yorùbá
-
Àlàkalẹ̀ àti ìlànà ètò eré ìtàgé
-
Ìpàlọ́ọ́
-
Ìwé eré ìtàgé
Ẹ̀kà 7 : Ẹ̀kọ́ gíga yorùbá
-
Ìwádìí àwọn ìwé olùkọ̀wé èdè yorùbá
-
Àlàkalẹ̀ àti ìlànà
-
Òwe
Ẹ̀kà 8 : Ìlò ẹ̀kọ́ èdè yorùbá fún sáyẹ́nsì àwùjọ
-
Ẹ̀kọ́ àwọn ọ̀rọ̀ èdè ìpìlẹ̀ ti ìṣòwò, ìtàja,
ìmọ̀ àwùjọ, ìbáaraẹnisọ̀rọ̀
Ẹ̀kà 9 : Ẹ̀kọ́ àwọn ọ̀rọ̀ èdè ìpìlẹ̀ ti ìmọ̀-ẹ̀rọ :
-
Ìmọ̀-ẹ̀rọ ìtanná, ìmọ̀-ẹ̀rọ iná mànàmáná,
ìmọ̀-ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀, ẹ̀rọ ìṣiṣẹ́
Ẹ̀kà 10 : Ìṣe ṣiṣe
Ìdiyélé ìkẹ́kọ́ wa ni € 10 aago kan;
Àpàpọ̀ ohun èlò ìkẹ́kọ́ máa wà níka ọwọ́ yin ti ìdiyélé ẹ jẹ́ € 25, inú àpàpọ̀ yìí a máa ri : Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé èdè yorùbá, ètò ìtẹ̀wé fóònù ayára àti ètò ìkọ́raẹnilẹ́kọ́ èdè yorùbá.
Ẹ ra ẹ̀rọ ìtẹ̀wé aláfọwọ́tẹ̀