Technology in Yorùbá

I Àwọn ẹ̀kọ́ ìmọ̀-ẹ̀rọ-ìtanná ( ẹ̀lẹ́ktrónìkì )

Àwọn adàìtanná-níwọ̀nba  ( Semikọ́ndọ́kítọ̀ )
Ẹ̀rọ ẹlẹ́nu méjì ( Díọ́dì )
Ẹ̀rọ ẹlẹ́nu mẹ́tà ( Tránsísítọ 1 )
Ìkọ́ṣẹ́ ìlò ẹ̀rọ ẹlẹ́nu mẹ́tà ( Tránsísítọ 2  )
Àtàkò ( Resistance )
Àrunpọ̀ wáyà ( Self )
Àtàkò oní àdáyípadà ( Frigistance)

 

I I  Ìmọ̀-ẹ̀rọ Àyára bíi àṣá ( Kọ́ńpútà )

 1)  Ẹ̀rọ Àyára bíi àṣá

Àwọn ẹ̀yà Àyára bíi àṣá ( Kọ́ńpútà )

 2)  Ẹ̀rọ ètò Àyára bíi àṣá

Αlúgórídímù ( Αlgorithm )
Αlákópọ̀ Java ( Java  )
Αlákópọ̀ C++ ( C++ )